Ọga ọlọpaa gboṣuba fun ọlọpaa to kọ miliọnu kan naira owo riba sọwọ afiniṣetutu


Awọn ikọ apaniṣọrọ naa pa Oyindamọla Adeyẹmi lọjọ kejidinlọgbọn oṣu kin-in-ni ọdun yii nilu Ijebu-Ode nipinlẹ Ogun.
Afurasi naa ti kọkọ sa mọ awọn ọlọpaa lọwọ nigba tọwọ tẹ awọn yooku rẹ, lọga ọlọpaa ba ni kiwọn fi ṣawari nitoripe ọwọ rẹ ni ẹsẹ mejeeji ọmọbinrin ti wọn pa naa wa
Nigbati wọn fọwọ ofin mu u nibi to lọọ fara ṣoko si lagbegbe Ijade-Iloti n'Ijebu-Ode, lo ba fi riba miliọnu kan naira lọ ọlọpaa to gba a mu ṣugbọn iyẹn kọ ọ,o si
 wọ de teṣan lọjọ Ẹti Furaidee to kọja

Comments

Popular posts from this blog

Àwọn ọmọ bíbí ìlú Òró bu ọlá fún ọba wọn tuntun

Wàhálà nlá nijọ sẹ̀lẹ́!Nítorí tùràrí wọ́n lu wòlíì lálùbami,làwọn aláṣẹ bá gbe ṣọ́ọ̀ṣì tìpa

Ojiṣẹ lṣẹdalẹ ṣatupalẹ ewi Wọle Ṣoyinka, 'Abiku' si ede Yoruba.