Yetunde Akilapa, Oṣere tiata to jale ti ha sọwọ ọlọpaa



Ọlọrun lo mọ̀ boya ṣe lọmọbinrin torukọ ẹ n jẹ Yetunde Akilapa oṣere onitiata yii ko nitiju toripe ọrọ gbogbo kii se lori alabahun lọrọ ẹ. 
Nibi to ti fọ ile onile wọle lọwọ ti tẹ ẹ pẹlu awọn dukia ẹni ẹlẹni to ji ko. 
Won ni bi ọmọbinrin naa ti maa n ṣe niyẹn nitori naa ni wọn ṣe sọpe boya afiṣe lọrọ rẹ. 
Lọdun 2015,lọwọ kọkọ tẹẹ lasiko to lọọ ji awọn eroja iṣerunlọṣọọ kan ko ninu ṣọọbu yiadirẹsa kan bakan naa ni wọn tun mu u lasiko to n ji ẹru ẹlẹru ko lọdun 2018 kọwọ to tun pada tẹ ẹ lọdun yii.

ÌṢẸ̀LẸ̀ KÀYÉÉFÌ

Comments

Popular posts from this blog

Àwọn ọmọ bíbí ìlú Òró bu ọlá fún ọba wọn tuntun

Wàhálà nlá nijọ sẹ̀lẹ́!Nítorí tùràrí wọ́n lu wòlíì lálùbami,làwọn aláṣẹ bá gbe ṣọ́ọ̀ṣì tìpa

Ojiṣẹ lṣẹdalẹ ṣatupalẹ ewi Wọle Ṣoyinka, 'Abiku' si ede Yoruba.