Pasítọ̀ yìí fún ọmọ ìyá méjì loyun pọ, inú ṣọ́ọ́ṣì ló ti n bá wọ́n ṣe kinní
Pasitọ Nduka Anyanwu kuro lori aga iwaasu, taarata lo gba ọgba ẹwọn lọ, titi ọjọ aye rẹ lo maa fi waasu nibẹ.
Awọn ọmọ iya meji ni pasitọ yii fun loyun pọ koda inu ṣọọṣi lo ti n bawọn fadura jagun titi ti kinni ọhun fi doyun.
Lẹyinti Onidaajọ Sọladoye dajọ ẹwọn gbere fun pasitọ naa tan, lo ni kawọn ọlọpaa lọ ko awọn obi awọn ọmọ naa wa lati wa sọ idi ti wọn fi ko ọmọ ọdun mẹtala ati mẹtadinlogun ṣikawọ ọkunrin ajeji to pe ara rẹ ni pasitọ
ÌWÀ Ọ̀DARÀN
Comments
Post a Comment