Ọọni Ile-Ifẹ kopa ninu fiimu agbelewo nilẹ Amẹrika, kabiesi ṣe atọna awọn ọmọ ilẹ oodua pada si orirun wọn
Ọọni Ile-Ife, Ọba Ẹniitan Adeyeye Ogunwusi, Ọjaja keji kopa ninu sinnima agbelewo nilẹ Amẹrika
Olootu fiimu naa sọpe "Ọba Adeyẹye, Ọọni kọkanlelaadọta nilẹ Oodua, ni apẹẹrẹ orirun ilẹ kaaro oojiire, ipa ti Ọọni ko naa ni lati ṣe atọna awọn ọmọ Yoruba pada si orisun wọn ninu fiimu naa ti wọn akọle ẹ ni ‘Take Me Home’.
Awọn oṣere mi-in to kopa ninu sinnima naa ni Abdullateef Adedimeji, Bayo Bankọle tawọn eeyan mọ si Boy Alinco.
Comments
Post a Comment