Ojo ni ẹ́ jàre,àwọn èèyàn sọ̀kò ọ̀rọ̀ sí Peter Obi bo ṣe ṣegbe lẹyin ijọba apapọ lori ọwọngogo naira


Awọn eeyan fikanra sọko ọrọ si Peter Obi, Oludije duop aarẹ labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Labour Party, bo ṣe gbawọn nimọran pe ki wọn farada ọwọngogo owo naira epo bẹntiro to n da wahala silẹ nigbooro nitoripe tiwọn naa ni ijọba apapọ n ṣe.
N lawọn eeyan ba sọrọ ọhun dorin lori ayelujara, wọn ni ojo lọkunrin naa, wọn ni ko laya lati sọ ootọ ọrọ bii Gomina ipinlẹ Eko tẹlẹ, Aṣiwaju Bọla Tinubu,Oludije dupo aarẹ labẹ ẹgbẹ oṣelu APC koda wọn ni ẹru n ba a lati sọrọ soke.

Comments

Popular posts from this blog

Àwọn ọmọ bíbí ìlú Òró bu ọlá fún ọba wọn tuntun

Wàhálà nlá nijọ sẹ̀lẹ́!Nítorí tùràrí wọ́n lu wòlíì lálùbami,làwọn aláṣẹ bá gbe ṣọ́ọ̀ṣì tìpa

Ojiṣẹ lṣẹdalẹ ṣatupalẹ ewi Wọle Ṣoyinka, 'Abiku' si ede Yoruba.